ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóòbù 33:16-18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Lẹ́yìn náà, ó máa ṣí etí wọn,+

      Ó sì máa tẹ* ìtọ́ni rẹ̀ mọ́ wọn lọ́kàn,

      17 Láti yí èèyàn kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀,+

      Kó sì gba èèyàn lọ́wọ́ ìgbéraga.+

      18 Ọlọ́run ò jẹ́ kí ọkàn* rẹ̀ wọnú kòtò,*+

      Kò jẹ́ kí idà* gba ẹ̀mí rẹ̀.

  • Àìsáyà 1:19, 20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Tó bá tinú yín wá, tí ẹ sì fetí sílẹ̀,

      Ẹ máa jẹ àwọn ohun rere ilẹ̀ náà.+

      20 Àmọ́ tí ẹ bá kọ̀, tí ẹ sì ṣọ̀tẹ̀,

      Idà máa jẹ yín run,+

      Torí Jèhófà ti fi ẹnu rẹ̀ sọ ọ́.”

  • Róòmù 2:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 àmọ́, fún àwọn tó jẹ́ alárìíyànjiyàn, tí wọ́n ń ṣàìgbọràn sí òtítọ́, tí wọ́n sì ń ṣègbọràn sí àìṣòdodo, ìrunú àti ìbínú yóò wá sórí wọn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́