Sáàmù 74:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 O pa ààlà sí gbogbo ayé;+O ṣe ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn àti ìgbà òtútù.+ Sáàmù 89:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Tìrẹ ni ọ̀run, tìrẹ sì ni ayé;+Ilẹ̀ tó ń méso jáde àti ohun tó kún inú rẹ̀,+ ìwọ lo fìdí wọn múlẹ̀.
11 Tìrẹ ni ọ̀run, tìrẹ sì ni ayé;+Ilẹ̀ tó ń méso jáde àti ohun tó kún inú rẹ̀,+ ìwọ lo fìdí wọn múlẹ̀.