Àìsáyà 45:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Mo dá ìmọ́lẹ̀,+ mo sì ṣe òkùnkùn,+Mo dá àlàáfíà,+ mo sì ṣe àjálù;+Èmi Jèhófà ni mò ń ṣe gbogbo nǹkan yìí.
7 Mo dá ìmọ́lẹ̀,+ mo sì ṣe òkùnkùn,+Mo dá àlàáfíà,+ mo sì ṣe àjálù;+Èmi Jèhófà ni mò ń ṣe gbogbo nǹkan yìí.