Ẹ́kísódù 15:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ìbẹ̀rù àti jìnnìjìnnì yóò bò wọ́n.+ Ọwọ́ ńlá rẹ yóò mú kí wọ́n dúró sójú kan bí òkúta Títí àwọn èèyàn rẹ yóò fi kọjá, Jèhófà, Títí àwọn èèyàn tí o mú jáde+ yóò fi kọjá.+ Ẹ́kísódù 23:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 “Màá mú kí àwọn èèyàn máa bẹ̀rù mi kí ẹ tó dé ọ̀dọ̀ wọn,+ màá sì da àárín gbogbo àwọn tí ẹ bá pàdé rú. Màá mú kí ẹ ṣẹ́gun gbogbo ọ̀tá yín, wọ́n á sì sá lọ.*+
16 Ìbẹ̀rù àti jìnnìjìnnì yóò bò wọ́n.+ Ọwọ́ ńlá rẹ yóò mú kí wọ́n dúró sójú kan bí òkúta Títí àwọn èèyàn rẹ yóò fi kọjá, Jèhófà, Títí àwọn èèyàn tí o mú jáde+ yóò fi kọjá.+
27 “Màá mú kí àwọn èèyàn máa bẹ̀rù mi kí ẹ tó dé ọ̀dọ̀ wọn,+ màá sì da àárín gbogbo àwọn tí ẹ bá pàdé rú. Màá mú kí ẹ ṣẹ́gun gbogbo ọ̀tá yín, wọ́n á sì sá lọ.*+