- 
	                        
            
            Àìsáyà 45:1, 2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        45 Ohun tí Jèhófà sọ fún ẹni tó yàn nìyí, fún Kírúsì,+ Ẹni tí mo di ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ mú,+ Láti tẹ àwọn orílẹ̀-èdè lórí ba níwájú rẹ̀,+ Láti gba ohun ìjà* àwọn ọba, Láti ṣí àwọn ilẹ̀kùn aláwẹ́ méjì níwájú rẹ̀, Kí wọ́n má sì ti àwọn ẹnubodè: Màá fọ́ àwọn ilẹ̀kùn bàbà sí wẹ́wẹ́, Màá sì gé àwọn ọ̀pá irin lulẹ̀.+ 
 
-