ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 31:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 “Ẹ kọ ọ̀rọ̀ orin yìí sílẹ̀ fún ara yín,+ kí ẹ sì fi kọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+ Ẹ fi kọ́ wọn,* kí orin yìí lè ṣe ẹlẹ́rìí mi lòdì sí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+

  • Jóṣúà 4:5-7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Jóṣúà sì sọ fún wọn pé: “Ẹ kọjá síwájú Àpótí Jèhófà Ọlọ́run yín, sí àárín Jọ́dánì, kí ẹnì kọ̀ọ̀kan yín sì gbé òkúta kan sí èjìká rẹ̀, kó jẹ́ iye ẹ̀yà àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, 6 kí èyí jẹ́ àmì fún yín. Tí àwọn ọmọ* yín bá bi yín lọ́jọ́ iwájú pé, ‘Kí ni ẹ̀ ń fi àwọn òkúta yìí ṣe?’+ 7 kí ẹ sọ fún wọn pé: ‘Torí omi odò Jọ́dánì tó dáwọ́ dúró níwájú àpótí+ májẹ̀mú Jèhófà ni. Nígbà tí wọ́n gbé àpótí náà sọdá odò Jọ́dánì, omi odò Jọ́dánì dáwọ́ dúró. Àwọn òkúta yìí máa jẹ́ ohun ìrántí fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì títí lọ.’”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́