Nọ́ńbà 15:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 ‘Kí ẹ máa ṣe wajawaja náà síbẹ̀, kí ẹ lè máa rí i, kó sì máa rán yín létí gbogbo àṣẹ Jèhófà, kí ẹ sì máa pa wọ́n mọ́.+ Ẹ ò gbọ́dọ̀ tẹ̀ lé ọkàn àti ojú yín tó ń mú kí ẹ lọ ṣe àgbèrè ẹ̀sìn.+ Òwe 4:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ọ̀ọ́kán tààrà ni kí ojú rẹ máa wò,Bẹ́ẹ̀ ni, iwájú rẹ gan-an ni kí o tẹjú* mọ́.+ Òwe 23:4, 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Má fi wàhálà pa ara rẹ torí kí o lè kó ọrọ̀ jọ.+ Fara balẹ̀ kí o sì lo òye.* 5 Nígbà tí o bá bojú wò ó, kò ní sí níbẹ̀,+Torí ó dájú pé ó máa hu ìyẹ́ bí ẹyẹ idì, á sì fò lọ sójú ọ̀run.+
39 ‘Kí ẹ máa ṣe wajawaja náà síbẹ̀, kí ẹ lè máa rí i, kó sì máa rán yín létí gbogbo àṣẹ Jèhófà, kí ẹ sì máa pa wọ́n mọ́.+ Ẹ ò gbọ́dọ̀ tẹ̀ lé ọkàn àti ojú yín tó ń mú kí ẹ lọ ṣe àgbèrè ẹ̀sìn.+
4 Má fi wàhálà pa ara rẹ torí kí o lè kó ọrọ̀ jọ.+ Fara balẹ̀ kí o sì lo òye.* 5 Nígbà tí o bá bojú wò ó, kò ní sí níbẹ̀,+Torí ó dájú pé ó máa hu ìyẹ́ bí ẹyẹ idì, á sì fò lọ sójú ọ̀run.+