1 Àwọn Ọba 3:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Torí náà, fún ìránṣẹ́ rẹ ní ọkàn tó ń gbọ́ràn láti máa fi ṣe ìdájọ́ àwọn èèyàn rẹ,+ láti fi mọ ìyàtọ̀ láàárín rere àti búburú,+ torí ta ló lè ṣe ìdájọ́ àwọn èèyàn rẹ tó pọ̀ gan-an* yìí?” Sáàmù 94:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ẹni tó ń tọ́ àwọn orílẹ̀-èdè sọ́nà, ṣé kò lè báni wí ni?+ Òun ló ń fún àwọn èèyàn ní ìmọ̀!+ Dáníẹ́lì 2:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ó ń yí ìgbà àti àsìkò pa dà,+Ó ń mú ọba kúrò, ó sì ń fi ọba jẹ,+Ó ń fún àwọn ọlọ́gbọ́n ní ọgbọ́n, ó sì ń fún àwọn tó ní òye ní ìmọ̀.+ Fílípì 1:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ohun tí mò ń gbà ládùúrà ni pé kí ìfẹ́ yín lè túbọ̀ pọ̀ gidigidi,+ kí ẹ sì ní ìmọ̀ tó péye+ àti òye tó kún rẹ́rẹ́;+
9 Torí náà, fún ìránṣẹ́ rẹ ní ọkàn tó ń gbọ́ràn láti máa fi ṣe ìdájọ́ àwọn èèyàn rẹ,+ láti fi mọ ìyàtọ̀ láàárín rere àti búburú,+ torí ta ló lè ṣe ìdájọ́ àwọn èèyàn rẹ tó pọ̀ gan-an* yìí?”
21 Ó ń yí ìgbà àti àsìkò pa dà,+Ó ń mú ọba kúrò, ó sì ń fi ọba jẹ,+Ó ń fún àwọn ọlọ́gbọ́n ní ọgbọ́n, ó sì ń fún àwọn tó ní òye ní ìmọ̀.+
9 Ohun tí mò ń gbà ládùúrà ni pé kí ìfẹ́ yín lè túbọ̀ pọ̀ gidigidi,+ kí ẹ sì ní ìmọ̀ tó péye+ àti òye tó kún rẹ́rẹ́;+