Àìsáyà 6:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Mú kí ọkàn àwọn èèyàn yìí yigbì,+Mú kí etí wọn di,+Kí o sì lẹ ojú wọn pọ̀,Kí wọ́n má bàa fi ojú wọn ríran,Kí wọ́n má sì fi etí wọn gbọ́rọ̀,Kí ọkàn wọn má bàa lóye,Kí wọ́n má bàa yí pa dà, kí wọ́n sì rí ìwòsàn.”+
10 Mú kí ọkàn àwọn èèyàn yìí yigbì,+Mú kí etí wọn di,+Kí o sì lẹ ojú wọn pọ̀,Kí wọ́n má bàa fi ojú wọn ríran,Kí wọ́n má sì fi etí wọn gbọ́rọ̀,Kí ọkàn wọn má bàa lóye,Kí wọ́n má bàa yí pa dà, kí wọ́n sì rí ìwòsàn.”+