Sáàmù 139:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ò ń kíyè sí* mi nígbà tí mo bá ń rìnrìn àjò àti nígbà tí mo bá dùbúlẹ̀;Gbogbo àwọn ọ̀nà mi ò ṣàjèjì sí ọ.+ Òwe 5:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Nítorí àwọn ọ̀nà èèyàn wà níwájú Jèhófà;Ó ń ṣàyẹ̀wò gbogbo ipa ọ̀nà rẹ̀.+ Òwe 15:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Isà Òkú* àti ibi ìparun* ṣí sílẹ̀ gbayawu lójú Jèhófà.+ Ká má ṣẹ̀ṣẹ̀ wá sọ ọkàn èèyàn!+ Hébérù 4:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Kò sí ìṣẹ̀dá kankan tó fara pa mọ́ ní ojú rẹ̀,+ àmọ́ ohun gbogbo wà ní ìhòòhò, ó sì wà ní gbangba lójú ẹni tí a gbọ́dọ̀ jíhìn fún.+
3 Ò ń kíyè sí* mi nígbà tí mo bá ń rìnrìn àjò àti nígbà tí mo bá dùbúlẹ̀;Gbogbo àwọn ọ̀nà mi ò ṣàjèjì sí ọ.+
13 Kò sí ìṣẹ̀dá kankan tó fara pa mọ́ ní ojú rẹ̀,+ àmọ́ ohun gbogbo wà ní ìhòòhò, ó sì wà ní gbangba lójú ẹni tí a gbọ́dọ̀ jíhìn fún.+