Sáàmù 46:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ọlọ́run wà nínú ìlú náà;+ kò ṣeé bì ṣubú. Ọlọ́run á ràn án lọ́wọ́ tí ilẹ̀ bá mọ́.+ Àìsáyà 24:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Òṣùpá àrànmọ́jú máa tẹ́,Ojú sì máa ti oòrùn tó ń ràn,+Torí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ti di Ọba+ ní Òkè Síónì+ àti ní Jerúsálẹ́mù,Ògo rẹ̀ ń tàn níwájú àwọn àgbààgbà àwọn èèyàn rẹ̀.*+
23 Òṣùpá àrànmọ́jú máa tẹ́,Ojú sì máa ti oòrùn tó ń ràn,+Torí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ti di Ọba+ ní Òkè Síónì+ àti ní Jerúsálẹ́mù,Ògo rẹ̀ ń tàn níwájú àwọn àgbààgbà àwọn èèyàn rẹ̀.*+