- 
	                        
            
            Jeremáyà 49:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        7 Sí Édómù, ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Ṣé kò sí ọgbọ́n mọ́ ní Témánì ni?+ Ṣé kò sí ìmọ̀ràn rere mọ́ lọ́dọ̀ àwọn olóye ni? Ṣé ọgbọ́n wọn ti jẹrà ni? 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Ọbadáyà 10-13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun