Àìsáyà 13:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ọ̀rọ̀ ìkéde sí Bábílónì,+ tí Àìsáyà+ ọmọ Émọ́ọ̀sì rí nínú ìran: Àìsáyà 13:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Bábílónì tó lógo* jù nínú àwọn ìjọba,+Ẹwà àti ògo àwọn ará Kálídíà,+Máa dà bíi Sódómù àti Gòmórà nígbà tí Ọlọ́run bì wọ́n ṣubú.+ Àìsáyà 14:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 o máa pa òwe* yìí sí ọba Bábílónì pé: “Ẹ wo bí òpin ṣe dé bá ẹni tó ń fipá kó àwọn míì ṣiṣẹ́! Ẹ wo bí ìfìyàjẹni ṣe wá sí òpin!+ Àìsáyà 14:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 “Màá sọ ọ́ di ibùgbé àwọn òòrẹ̀ àti agbègbè tó ní irà, màá sì fi ìgbálẹ̀ ìparun gbá a,”+ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí.
19 Bábílónì tó lógo* jù nínú àwọn ìjọba,+Ẹwà àti ògo àwọn ará Kálídíà,+Máa dà bíi Sódómù àti Gòmórà nígbà tí Ọlọ́run bì wọ́n ṣubú.+
4 o máa pa òwe* yìí sí ọba Bábílónì pé: “Ẹ wo bí òpin ṣe dé bá ẹni tó ń fipá kó àwọn míì ṣiṣẹ́! Ẹ wo bí ìfìyàjẹni ṣe wá sí òpin!+
23 “Màá sọ ọ́ di ibùgbé àwọn òòrẹ̀ àti agbègbè tó ní irà, màá sì fi ìgbálẹ̀ ìparun gbá a,”+ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí.