Léfítíkù 26:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Màá mú kí àlàáfíà wà ní ilẹ̀ náà,+ ẹ ó sì dùbúlẹ̀ láìsí ẹni tó máa dẹ́rù bà yín;+ màá mú àwọn ẹranko burúkú kúrò ní ilẹ̀ náà, idà ogun ò sì ní kọjá ní ilẹ̀ yín. Àìsáyà 60:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Dípò bàbà, màá mú wúrà wá,Dípò irin, màá mú fàdákà wáDípò igi, bàbàÀti dípò òkúta, irin;Màá fi àlàáfíà ṣe àwọn alábòójútó rẹ,Màá sì fi òdodo ṣe àwọn tó ń yan iṣẹ́ fún ọ.+
6 Màá mú kí àlàáfíà wà ní ilẹ̀ náà,+ ẹ ó sì dùbúlẹ̀ láìsí ẹni tó máa dẹ́rù bà yín;+ màá mú àwọn ẹranko burúkú kúrò ní ilẹ̀ náà, idà ogun ò sì ní kọjá ní ilẹ̀ yín.
17 Dípò bàbà, màá mú wúrà wá,Dípò irin, màá mú fàdákà wáDípò igi, bàbàÀti dípò òkúta, irin;Màá fi àlàáfíà ṣe àwọn alábòójútó rẹ,Màá sì fi òdodo ṣe àwọn tó ń yan iṣẹ́ fún ọ.+