Jẹ́nẹ́sísì 15:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Lẹ́yìn èyí, Jèhófà sọ fún Ábúrámù nínú ìran pé: “Ábúrámù, má bẹ̀rù.+ Apata ni mo jẹ́ fún ọ.+ Èrè rẹ yóò pọ̀ gan-an.”+ Jẹ́nẹ́sísì 15:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ábúrámù ní ìgbàgbọ́ nínú Jèhófà,+ Ó sì kà á sí òdodo fún un.+
15 Lẹ́yìn èyí, Jèhófà sọ fún Ábúrámù nínú ìran pé: “Ábúrámù, má bẹ̀rù.+ Apata ni mo jẹ́ fún ọ.+ Èrè rẹ yóò pọ̀ gan-an.”+