-
Sáàmù 35:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Nígbà náà, èmi yóò máa dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ nínú ìjọ ńlá;+
Èmi yóò máa yìn ọ́ láàárín ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn.
-
-
Sáàmù 40:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Mi ò bo òdodo rẹ mọ́lẹ̀ nínú ọkàn mi.
Mo kéde ìṣòtítọ́ rẹ àti ìgbàlà rẹ.
Mi ò fi ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ àti òtítọ́ rẹ pa mọ́ nínú ìjọ ńlá.”+
-
-
Sáàmù 111:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Màá fi gbogbo ọkàn mi yin Jèhófà+
ב [Bétì]
Nínú àwùjọ àwọn adúróṣinṣin àti nínú ìjọ.
-