- 
	                        
            
            Sáàmù 128:1-5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        2 Wàá jẹ ohun tí ọwọ́ rẹ ṣiṣẹ́ kára láti mú jáde. Wàá láyọ̀, wàá sì láásìkí.+ 3 Ìyàwó rẹ yóò dà bí igi àjàrà tó ń so nínú ilé rẹ;+ Àwọn ọmọ rẹ yóò dà bí àwọn ẹ̀ka tó ṣẹ̀ṣẹ̀ yọ lára igi ólífì, wọ́n á yí tábìlì rẹ ká. 4 Wò ó! Bí ọkùnrin tó bẹ̀rù Jèhófà Ṣe máa rí ìbùkún gbà nìyẹn.+ 5 Jèhófà yóò bù kún ọ láti Síónì. Kí aásìkí Jerúsálẹ́mù ṣojú rẹ ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ,+ 
 
-