Jóòbù 37:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ó kọjá agbára wa láti lóye Olódùmarè;+Agbára rẹ̀ pọ̀ gan-an,+Kì í ṣe ohun tó lòdì sí ìdájọ́ òdodo+ rẹ̀ àti òdodo rẹ̀ tó pọ̀ gidigidi.+ Sáàmù 11:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nítorí olódodo ni Jèhófà;+ ó nífẹ̀ẹ́ àwọn iṣẹ́ òdodo.+ Àwọn adúróṣinṣin yóò rí ojú* rẹ̀.+ Sáàmù 45:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 O nífẹ̀ẹ́ òdodo,+ o sì kórìíra ìwà burúkú.+ Ìdí nìyẹn tí Ọlọ́run, àní Ọlọ́run rẹ, fi fòróró ayọ̀+ yàn ọ́+ ju àwọn ojúgbà rẹ.
23 Ó kọjá agbára wa láti lóye Olódùmarè;+Agbára rẹ̀ pọ̀ gan-an,+Kì í ṣe ohun tó lòdì sí ìdájọ́ òdodo+ rẹ̀ àti òdodo rẹ̀ tó pọ̀ gidigidi.+
7 O nífẹ̀ẹ́ òdodo,+ o sì kórìíra ìwà burúkú.+ Ìdí nìyẹn tí Ọlọ́run, àní Ọlọ́run rẹ, fi fòróró ayọ̀+ yàn ọ́+ ju àwọn ojúgbà rẹ.