-
Sáàmù 40:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Kí ìtìjú àti ẹ̀tẹ́ bá
Gbogbo àwọn tó fẹ́ gba ẹ̀mí mi.*
Kí àwọn tí inú wọn ń dùn sí àjálù tó bá mi
Sá pa dà nínú ẹ̀tẹ́.
-
14 Kí ìtìjú àti ẹ̀tẹ́ bá
Gbogbo àwọn tó fẹ́ gba ẹ̀mí mi.*
Kí àwọn tí inú wọn ń dùn sí àjálù tó bá mi
Sá pa dà nínú ẹ̀tẹ́.