ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 27:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Nígbà tí àwọn ẹni ibi gbéjà kò mí láti jẹ ẹran ara mi,+

      Àwọn elénìní mi àti àwọn ọ̀tá mi ló kọsẹ̀ tí wọ́n sì ṣubú.

  • Jeremáyà 15:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Ìwọ fúnra rẹ mọ̀, Jèhófà,

      Rántí mi kí o sì kíyè sí mi.

      Gbẹ̀san mi lára àwọn tó ń ṣe inúnibíni sí mi.+

      Má ṣe jẹ́ kí n ṣègbé* torí o kì í tètè bínú.

      O ṣáà mọ̀ pé nítorí rẹ ni mo ṣe ń fara da ẹ̀gàn yìí.+

  • Jeremáyà 15:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 “Màá sọ ọ́ di odi bàbà tó lágbára sí àwọn èèyàn yìí.+

      Ó dájú pé wọ́n á bá ọ jà,

      Àmọ́ wọn ò ní borí* rẹ,+

      Torí mo wà pẹ̀lú rẹ, láti gbà ọ́ àti láti dá ọ sílẹ̀,” ni Jèhófà wí.

  • Jeremáyà 17:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Jẹ́ kí ojú ti àwọn tó ń ṣe inúnibíni sí mi,+

      Àmọ́ má ṣe jẹ́ kí ojú tì mí.

      Jẹ́ kí jìnnìjìnnì bá wọn,

      Àmọ́ má ṣe jẹ́ kí jìnnìjìnnì bá mi.

      Mú kí ọjọ́ àjálù dé bá wọn,+

      Fọ́ wọn túútúú, kí o sì pa wọ́n run pátápátá.*

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́