Àìsáyà 50:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ ti ṣí etí mi,Mi ò sì ya ọlọ̀tẹ̀.+ Mi ò yíjú sí òdìkejì.+