Mátíù 26:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Ó lọ síwájú díẹ̀, ó dojú bolẹ̀, ó sì gbàdúrà pé:+ “Baba mi, tó bá ṣeé ṣe, jẹ́ kí ife+ yìí ré mi kọjá. Síbẹ̀, kì í ṣe bí mo ṣe fẹ́, àmọ́ bí ìwọ ṣe fẹ́.”+ Fílípì 2:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Jù bẹ́ẹ̀ lọ, nígbà tó wá ní ìrí èèyàn,* ó rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀, ó sì di onígbọràn títí dé ojú ikú,+ bẹ́ẹ̀ ni, ikú lórí òpó igi oró.*+
39 Ó lọ síwájú díẹ̀, ó dojú bolẹ̀, ó sì gbàdúrà pé:+ “Baba mi, tó bá ṣeé ṣe, jẹ́ kí ife+ yìí ré mi kọjá. Síbẹ̀, kì í ṣe bí mo ṣe fẹ́, àmọ́ bí ìwọ ṣe fẹ́.”+
8 Jù bẹ́ẹ̀ lọ, nígbà tó wá ní ìrí èèyàn,* ó rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀, ó sì di onígbọràn títí dé ojú ikú,+ bẹ́ẹ̀ ni, ikú lórí òpó igi oró.*+