6 Ẹbọ àti ọrẹ kọ́ ni ohun tó wù ọ́,+
Àmọ́ o la etí mi sílẹ̀ kí n lè gbọ́.+
O kò béèrè ẹbọ sísun àti ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀.+
7 Lẹ́yìn náà, mo sọ pé: “Wò ó, mo ti dé.
A ti kọ ọ́ nípa mi sínú àkájọ ìwé.+
8 Láti ṣe ìfẹ́ rẹ, Ọlọ́run mi, ni inú mi dùn sí,+
Òfin rẹ sì wà nínú mi lọ́hùn-ún.+