- 
	                        
            
            Sáàmù 9:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        4 Nítorí pé o gbèjà mi lórí ẹ̀tọ́ mi; O jókòó sórí ìtẹ́ rẹ, o sì ń fi òdodo ṣe ìdájọ́.+ 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Sáàmù 98:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        9 Níwájú Jèhófà, nítorí ó ń bọ̀ wá* ṣe ìdájọ́ ayé. 
 
-