Diutarónómì 32:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Báwo ni ẹnì kan ṣe lè lé ẹgbẹ̀rún kan (1,000),Kí ẹni méjì sì mú kí ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) sá?+ Tí kì í bá ṣe pé Àpáta wọn ti tà wọ́n,+Tí Jèhófà sì ti fi wọ́n lé ọ̀tá lọ́wọ́.
30 Báwo ni ẹnì kan ṣe lè lé ẹgbẹ̀rún kan (1,000),Kí ẹni méjì sì mú kí ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) sá?+ Tí kì í bá ṣe pé Àpáta wọn ti tà wọ́n,+Tí Jèhófà sì ti fi wọ́n lé ọ̀tá lọ́wọ́.