Jóòbù 28:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ó sì sọ fún èèyàn pé: ‘Wò ó! Ìbẹ̀rù Jèhófà ni ọgbọ́n,+Yíyẹra fún ìwà burúkú sì ni òye.’”+ Òwe 9:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ìbẹ̀rù Jèhófà ni ìbẹ̀rẹ̀ ọgbọ́n,+Ìmọ̀ Ẹni Mímọ́ Jù Lọ+ sì ni òye.