Òwe 6:32, 33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Ẹni tó bá bá obìnrin ṣe àgbèrè kò ní làákàyè;*Ẹni tó bá ṣe bẹ́ẹ̀ ń fa ìparun bá ara* rẹ̀.+ 33 Ọgbẹ́ àti àbùkù ló máa gbà,+Ìtìjú rẹ̀ kò sì ní pa rẹ́.+
32 Ẹni tó bá bá obìnrin ṣe àgbèrè kò ní làákàyè;*Ẹni tó bá ṣe bẹ́ẹ̀ ń fa ìparun bá ara* rẹ̀.+ 33 Ọgbẹ́ àti àbùkù ló máa gbà,+Ìtìjú rẹ̀ kò sì ní pa rẹ́.+