-
Diutarónómì 21:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Kí gbogbo ọkùnrin ìlú rẹ̀ sọ ọ́ ní òkúta pa. Kí o mú ohun tó burú kúrò láàárín rẹ, tí gbogbo Ísírẹ́lì bá sì gbọ́, ẹ̀rù á bà wọ́n.+
-