Òwe 6:16-18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ohun mẹ́fà wà tí Jèhófà kórìíra;Bẹ́ẹ̀ ni, ohun méje tó jẹ́ ohun ìríra fún un:* 17 Ojú ìgbéraga,+ ahọ́n èké+ àti ọwọ́ tó ń ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀,+18 Ọkàn tó ń gbèrò ìkà+ àti ẹsẹ̀ tó ń sáré tete láti ṣe ibi, Róòmù 3:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “Ẹsẹ̀ wọn yá nílẹ̀ láti ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀.”+
16 Ohun mẹ́fà wà tí Jèhófà kórìíra;Bẹ́ẹ̀ ni, ohun méje tó jẹ́ ohun ìríra fún un:* 17 Ojú ìgbéraga,+ ahọ́n èké+ àti ọwọ́ tó ń ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀,+18 Ọkàn tó ń gbèrò ìkà+ àti ẹsẹ̀ tó ń sáré tete láti ṣe ibi, Róòmù 3:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “Ẹsẹ̀ wọn yá nílẹ̀ láti ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀.”+