-
Sáàmù 119:34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
34 Jẹ́ kí n ní òye,
Kí n lè máa tẹ̀ lé òfin rẹ,
Kí n sì máa fi gbogbo ọkàn mi pa á mọ́.
-
-
Sáàmù 119:100Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
100 Mò ń fi òye hùwà ju àwọn àgbààgbà lọ,
Nítorí pé mò ń pa àwọn àṣẹ rẹ mọ́.
-