10 Kí o lawọ́ sí i dáadáa,+ kí o* má sì ráhùn tí o bá ń fún un, torí èyí á mú kí Jèhófà Ọlọ́run rẹ bù kún ọ nínú gbogbo ohun tí o bá ń ṣe àtàwọn ohun tí o bá dáwọ́ lé.+
11Fọ́n* oúnjẹ rẹ sí ojú omi,+ torí pé lẹ́yìn ọjọ́ púpọ̀, wàá tún rí i.+2 Pín in fún àwọn méje tàbí mẹ́jọ pàápàá,+ nítorí o kò mọ àjálù tó máa dé bá ayé.