Jóòbù 28:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ó sì sọ fún èèyàn pé: ‘Wò ó! Ìbẹ̀rù Jèhófà ni ọgbọ́n,+Yíyẹra fún ìwà burúkú sì ni òye.’”+ Òwe 8:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ìbẹ̀rù Jèhófà ni ìkórìíra ohun búburú.+ Mo kórìíra ìṣefọ́nńté àti ìgbéraga+ àti ọ̀nà ibi àti ọ̀rọ̀ àyídáyidà.+ Jeremáyà 32:40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Màá sì bá wọn dá májẹ̀mú tó máa wà títí láé,+ pé mi ò ní jáwọ́ nínú ṣíṣe rere fún wọn;+ màá fi ìbẹ̀rù mi sínú ọkàn wọn, kí wọ́n má bàa kúrò lọ́dọ̀ mi.+
13 Ìbẹ̀rù Jèhófà ni ìkórìíra ohun búburú.+ Mo kórìíra ìṣefọ́nńté àti ìgbéraga+ àti ọ̀nà ibi àti ọ̀rọ̀ àyídáyidà.+
40 Màá sì bá wọn dá májẹ̀mú tó máa wà títí láé,+ pé mi ò ní jáwọ́ nínú ṣíṣe rere fún wọn;+ màá fi ìbẹ̀rù mi sínú ọkàn wọn, kí wọ́n má bàa kúrò lọ́dọ̀ mi.+