ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 9:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 “Ṣùgbọ́n kí ẹni tó bá fẹ́ yangàn máa yangàn nítorí ohun yìí:

      Pé òun ní ìjìnlẹ̀ òye àti ìmọ̀ nípa mi,+

      Pé èmi ni Jèhófà, Ẹni tí ìfẹ́ rẹ̀ kì í yẹ̀, tó ń ṣe ìdájọ́ tí ó tọ́ àti òdodo ní ayé,+

      Nítorí nǹkan wọ̀nyí ni inú mi dùn sí,”+ ni Jèhófà wí.

  • 1 Jòhánù 5:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Ṣùgbọ́n a mọ̀ pé Ọmọ Ọlọ́run ti wá,+ ó sì ti jẹ́ ká ní òye* ká lè mọ ẹni tòótọ́ náà. A sì wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú ẹni tòótọ́ náà,+ nípasẹ̀ Jésù Kristi Ọmọ rẹ̀. Èyí ni Ọlọ́run tòótọ́ náà àti ìyè àìnípẹ̀kun.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́