Jẹ́nẹ́sísì 2:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ìdí nìyẹn tí ọkùnrin á ṣe fi bàbá rẹ̀ àti ìyá rẹ̀ sílẹ̀, á sì fà mọ́* ìyàwó rẹ̀, wọ́n á sì di ara kan.+ Òwe 5:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Kí orísun omi* rẹ ní ìbùkún,Kí o sì máa yọ̀ pẹ̀lú aya ìgbà èwe rẹ,+
24 Ìdí nìyẹn tí ọkùnrin á ṣe fi bàbá rẹ̀ àti ìyá rẹ̀ sílẹ̀, á sì fà mọ́* ìyàwó rẹ̀, wọ́n á sì di ara kan.+