-
2 Sámúẹ́lì 16:21, 22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Áhítófẹ́lì wá sọ fún Ábúsálómù pé: “Bá àwọn wáhàrì* bàbá rẹ lò pọ̀,+ àwọn tó fi sílẹ̀ pé kí wọ́n máa tọ́jú ilé.*+ Gbogbo Ísírẹ́lì á wá gbọ́ pé o ti sọ ara rẹ di ẹni ìkórìíra lójú bàbá rẹ, ọkàn gbogbo àwọn tó ń tì ọ́ lẹ́yìn á sì balẹ̀.” 22 Nítorí náà, wọ́n pa àgọ́ kan fún Ábúsálómù sórí òrùlé,+ Ábúsálómù sì bá àwọn wáhàrì bàbá rẹ̀ lò pọ̀+ níṣojú gbogbo Ísírẹ́lì.+
-