Léfítíkù 18:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “‘O ò gbọ́dọ̀ bá ìyàwó bàbá rẹ lò pọ̀.+ Ìyẹn máa dójú ti bàbá rẹ.* Léfítíkù 20:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ọkùnrin tó bá bá ìyàwó bàbá rẹ̀ sùn ti dójú ti* bàbá rẹ̀.+ Ẹ gbọ́dọ̀ pa àwọn méjèèjì. Ẹ̀jẹ̀ wọn wà lórí wọn. 1 Àwọn Ọba 2:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ni Ọba Sólómọ́nì bá dá ìyá rẹ̀ lóhùn pé: “Kí ló dé tí o fi ní kí n fún Ádóníjà ní Ábíṣágì ará Ṣúnémù? Ò bá kúkú ní kí n fún un ní ìjọba pẹ̀lú+ nítorí pé ẹ̀gbọ́n mi ni,+ ẹ̀yìn rẹ̀ sì ni àlùfáà Ábíátárì àti Jóábù+ ọmọ Seruáyà+ wà.”
11 Ọkùnrin tó bá bá ìyàwó bàbá rẹ̀ sùn ti dójú ti* bàbá rẹ̀.+ Ẹ gbọ́dọ̀ pa àwọn méjèèjì. Ẹ̀jẹ̀ wọn wà lórí wọn.
22 Ni Ọba Sólómọ́nì bá dá ìyá rẹ̀ lóhùn pé: “Kí ló dé tí o fi ní kí n fún Ádóníjà ní Ábíṣágì ará Ṣúnémù? Ò bá kúkú ní kí n fún un ní ìjọba pẹ̀lú+ nítorí pé ẹ̀gbọ́n mi ni,+ ẹ̀yìn rẹ̀ sì ni àlùfáà Ábíátárì àti Jóábù+ ọmọ Seruáyà+ wà.”