Òwe 28:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Aláyọ̀ ni ẹni tó bá ń kíyè sára* nígbà gbogbo,Àmọ́ ẹni tó bá ń sé ọkàn rẹ̀ le yóò ṣubú sínú ìyọnu.+ Òwe 29:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ẹni tó ń mú ọrùn rẹ̀ le* lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìbáwí +Yóò pa run lójijì láìsí àtúnṣe.+
14 Aláyọ̀ ni ẹni tó bá ń kíyè sára* nígbà gbogbo,Àmọ́ ẹni tó bá ń sé ọkàn rẹ̀ le yóò ṣubú sínú ìyọnu.+