Òwe 13:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ẹni tó bá fa ọ̀pá* sẹ́yìn kórìíra ọmọ rẹ̀,+Àmọ́ ẹni tó bá nífẹ̀ẹ́ ọmọ rẹ̀ máa ń bá a wí dáadáa.*+ Òwe 19:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Bá ọmọ rẹ wí nígbà tí ìrètí ṣì wà,+Kí o má bàa jẹ̀bi* ikú rẹ̀.+ Éfésù 6:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ̀yin bàbá, ẹ má ṣe máa mú àwọn ọmọ yín bínú,+ kàkà bẹ́ẹ̀, ẹ máa tọ́ wọn dàgbà nínú ìbáwí+ àti ìmọ̀ràn* Jèhófà.*+
4 Ẹ̀yin bàbá, ẹ má ṣe máa mú àwọn ọmọ yín bínú,+ kàkà bẹ́ẹ̀, ẹ máa tọ́ wọn dàgbà nínú ìbáwí+ àti ìmọ̀ràn* Jèhófà.*+