Òwe 27:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ọmọ mi, jẹ́ ọlọ́gbọ́n, kí o sì mú ọkàn mi yọ̀,+Kí n lè fún ẹni tó ń pẹ̀gàn mi lésì.+ 3 Jòhánù 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Kò sí ohun tó ń mú inú mi dùn* bíi kí n máa gbọ́ pé àwọn ọmọ mi ń rìn nínú òtítọ́.+