Òwe 18:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ẹni tó bá kọ́kọ́ ro ẹjọ́ rẹ̀ ló ń dà bíi pé ó jàre,+Títí ẹnì kejì fi wá, tó sì bi í ní ìbéèrè.*+ Mátíù 5:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 “Tètè yanjú ọ̀rọ̀ pẹ̀lú ẹni tó fẹ̀sùn kàn ọ́ lábẹ́ òfin, nígbà tí o wà pẹ̀lú rẹ̀ lójú ọ̀nà ibẹ̀, kí ẹni tó fẹ̀sùn kàn ọ́ má bàa fi ọ́ lé adájọ́ lọ́wọ́ lọ́nà kan ṣáá, kí adájọ́ sì fi ọ́ lé òṣìṣẹ́ ilé ẹjọ́ lọ́wọ́, kí wọ́n sì fi ọ́ sẹ́wọ̀n.+
25 “Tètè yanjú ọ̀rọ̀ pẹ̀lú ẹni tó fẹ̀sùn kàn ọ́ lábẹ́ òfin, nígbà tí o wà pẹ̀lú rẹ̀ lójú ọ̀nà ibẹ̀, kí ẹni tó fẹ̀sùn kàn ọ́ má bàa fi ọ́ lé adájọ́ lọ́wọ́ lọ́nà kan ṣáá, kí adájọ́ sì fi ọ́ lé òṣìṣẹ́ ilé ẹjọ́ lọ́wọ́, kí wọ́n sì fi ọ́ sẹ́wọ̀n.+