Sáàmù 27:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nítorí yóò fi mí pa mọ́ sí ibi kọ́lọ́fín rẹ̀ ní ọjọ́ àjálù;+Yóò tọ́jú mi pa mọ́ sí ibi ìkọ̀kọ̀ àgọ́ rẹ̀;+Yóò gbé mi sórí àpáta.+ Sáàmù 91:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Yóò fi àwọn ìyẹ́ tó fi ń fò bò ọ́,*Wàá sì fi abẹ́ ìyẹ́ apá rẹ̀ ṣe ibi ààbò.+ Òtítọ́ rẹ̀+ yóò jẹ́ apata+ ńlá àti odi* ààbò.
5 Nítorí yóò fi mí pa mọ́ sí ibi kọ́lọ́fín rẹ̀ ní ọjọ́ àjálù;+Yóò tọ́jú mi pa mọ́ sí ibi ìkọ̀kọ̀ àgọ́ rẹ̀;+Yóò gbé mi sórí àpáta.+
4 Yóò fi àwọn ìyẹ́ tó fi ń fò bò ọ́,*Wàá sì fi abẹ́ ìyẹ́ apá rẹ̀ ṣe ibi ààbò.+ Òtítọ́ rẹ̀+ yóò jẹ́ apata+ ńlá àti odi* ààbò.