Òwe 18:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ọ̀rọ̀ ẹnu òmùgọ̀ máa ń dá ìjà sílẹ̀,+Ẹnu rẹ̀ sì máa ń mú kí wọ́n lù ú.+ Òwe 20:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ògo ló jẹ́ fún èèyàn láti yẹra fún ìjà,+Àmọ́ àwọn òmùgọ̀ jẹ́ aríjàgbá.+