ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóòbù 3:17-19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Ibẹ̀ ni àwọn ẹni burúkú pàápàá ti bọ́ lọ́wọ́ ìdààmú;

      Ibẹ̀ ni àwọn tí kò lókun ti ń sinmi.+

      18 Ibẹ̀ ni ara ti tu àwọn ẹlẹ́wọ̀n pa pọ̀;

      Wọn ò gbọ́ ohùn ẹni tó ń fipá kó wọn ṣiṣẹ́.

      19 Ẹni kékeré àti ẹni ńlá ò jura wọn lọ níbẹ̀,+

      Ẹrú sì dòmìnira lọ́wọ́ ọ̀gá rẹ̀.

  • Oníwàásù 2:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Lẹ́yìn náà, mo sọ lọ́kàn mi pé: “Ohun tó ṣẹlẹ̀ sí òmùgọ̀ ló máa ṣẹlẹ̀ sí èmi náà.”+ Kí wá ni èrè ọgbọ́n tí mo gbọ́n ní àgbọ́njù? Mo sì sọ lọ́kàn mi pé: “Asán ni èyí pẹ̀lú.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́