Oníwàásù 1:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Mo rí gbogbo iṣẹ́ tí a ṣe lábẹ́ ọ̀run,* Sì wò ó! asán ni gbogbo rẹ̀, ìmúlẹ̀mófo.*+ Oníwàásù 5:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Èyí pẹ̀lú jẹ́ àdánù* ńlá: Bí ẹni náà ṣe wá gẹ́lẹ́, bẹ́ẹ̀ ló ṣe máa lọ; èrè wo ló sì wà fún ẹni tó ń ṣiṣẹ́ kára lórí asán?+
16 Èyí pẹ̀lú jẹ́ àdánù* ńlá: Bí ẹni náà ṣe wá gẹ́lẹ́, bẹ́ẹ̀ ló ṣe máa lọ; èrè wo ló sì wà fún ẹni tó ń ṣiṣẹ́ kára lórí asán?+