-
Jóòbù 14:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Àmọ́ èèyàn kú, ó sì wà nílẹ̀ láìlágbára;
Tí èèyàn bá gbẹ́mìí mì, ibo ló wà?+
-
-
Sáàmù 39:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Ní ti ọmọ èèyàn, bó tilẹ̀ dà bíi pé kò sí nínú ewu, bí èémí lásán ló rí.+ (Sélà)
-