ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 37:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Ohun díẹ̀ tí olódodo ní

      Sàn ju ọ̀pọ̀ nǹkan tí àwọn ẹni burúkú ní.+

  • Òwe 15:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Ó sàn kéèyàn ní díẹ̀, kó sì bẹ̀rù Jèhófà+

      Ju kó ní ọ̀pọ̀ ọrọ̀ pẹ̀lú àníyàn.*+

  • Òwe 16:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Ó sàn kéèyàn ní díẹ̀ àmọ́ kó jẹ́ olóòótọ́+

      Ju kéèyàn fi èrú kó èrè púpọ̀ jọ.+

  • Òwe 17:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Òkèlè* gbígbẹ níbi tí àlàáfíà wà*+

      Sàn ju ilé àsè* rẹpẹtẹ tí ìjà wà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́