Oníwàásù 2:22, 23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Kí tiẹ̀ ni èrè tí èèyàn rí jẹ nínú gbogbo iṣẹ́ àṣekára rẹ̀ àti gbogbo bó ṣe ń wù ú* láti ṣiṣẹ́ kára lábẹ́ ọ̀run?*+ 23 Torí ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀, iṣẹ́ rẹ̀ ń mú ìrora àti ìjákulẹ̀ bá a,+ kódà kì í rí oorun sùn lóru.+ Asán ni èyí pẹ̀lú.
22 Kí tiẹ̀ ni èrè tí èèyàn rí jẹ nínú gbogbo iṣẹ́ àṣekára rẹ̀ àti gbogbo bó ṣe ń wù ú* láti ṣiṣẹ́ kára lábẹ́ ọ̀run?*+ 23 Torí ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀, iṣẹ́ rẹ̀ ń mú ìrora àti ìjákulẹ̀ bá a,+ kódà kì í rí oorun sùn lóru.+ Asán ni èyí pẹ̀lú.