Àìsáyà 43:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 “Ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí mi,”+ ni Jèhófà wí,“Àní ìránṣẹ́ mi tí mo ti yàn,+Kí ẹ lè mọ̀, kí ẹ sì ní ìgbàgbọ́ nínú mi,*Kó sì yé yín pé Ẹnì kan náà ni mí.+ Ṣáájú mi, kò sí Ọlọ́run tí a dá,Lẹ́yìn mi, kò sí ìkankan.+ Àìsáyà 44:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,Ọba Ísírẹ́lì+ àti Olùtúnrà rẹ̀,+ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun: ‘Èmi ni ẹni àkọ́kọ́ àti ẹni ìkẹyìn.+ Kò sí Ọlọ́run kankan àfi èmi.+ Àìsáyà 48:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Fetí sí mi, ìwọ Jékọ́bù àti ìwọ Ísírẹ́lì, ẹni tí mo ti pè,Ẹnì kan náà ni mí.+ Èmi ni ẹni àkọ́kọ́; èmi náà ni ẹni ìkẹyìn.+ Ìfihàn 1:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Jèhófà* Ọlọ́run sọ pé, “Èmi ni Ááfà àti Ómégà,*+ Ẹni tó ti wà tipẹ́, tó wà báyìí, tó sì ń bọ̀, Olódùmarè.”+
10 “Ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí mi,”+ ni Jèhófà wí,“Àní ìránṣẹ́ mi tí mo ti yàn,+Kí ẹ lè mọ̀, kí ẹ sì ní ìgbàgbọ́ nínú mi,*Kó sì yé yín pé Ẹnì kan náà ni mí.+ Ṣáájú mi, kò sí Ọlọ́run tí a dá,Lẹ́yìn mi, kò sí ìkankan.+
6 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,Ọba Ísírẹ́lì+ àti Olùtúnrà rẹ̀,+ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun: ‘Èmi ni ẹni àkọ́kọ́ àti ẹni ìkẹyìn.+ Kò sí Ọlọ́run kankan àfi èmi.+
12 Fetí sí mi, ìwọ Jékọ́bù àti ìwọ Ísírẹ́lì, ẹni tí mo ti pè,Ẹnì kan náà ni mí.+ Èmi ni ẹni àkọ́kọ́; èmi náà ni ẹni ìkẹyìn.+
8 Jèhófà* Ọlọ́run sọ pé, “Èmi ni Ááfà àti Ómégà,*+ Ẹni tó ti wà tipẹ́, tó wà báyìí, tó sì ń bọ̀, Olódùmarè.”+