ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 49:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Ó sọ pé: “Ti pé o jẹ́ ìránṣẹ́ mi nìkan ò tó,

      Láti gbé àwọn ẹ̀yà Jékọ́bù dìde,

      Kí o sì mú àwọn tí a dá sí lára Ísírẹ́lì pa dà.

      Mo tún ti fi ọ́ ṣe ìmọ́lẹ̀ àwọn orílẹ̀-èdè,+

      Kí ìgbàlà mi lè dé gbogbo ayé.”+

  • Lúùkù 2:29-32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 “Ní báyìí, Olúwa Ọba Aláṣẹ, ò ń jẹ́ kí ẹrú rẹ lọ ní àlàáfíà+ bí o ṣe kéde, 30 torí ojú mi ti rí ohun tí o máa fi gbani là,+ 31 èyí tí o pèsè níṣojú gbogbo èèyàn,+ 32 ìmọ́lẹ̀+ láti mú ìbòjú kúrò lójú àwọn orílẹ̀-èdè+ àti ògo àwọn èèyàn rẹ Ísírẹ́lì.”

  • Jòhánù 8:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 12 Jésù tún sọ fún wọn pé: “Èmi ni ìmọ́lẹ̀ ayé.+ Ó dájú pé ẹnikẹ́ni tó bá ń tẹ̀ lé mi kò ní rìn nínú òkùnkùn, àmọ́ ó máa ní ìmọ́lẹ̀+ ìyè.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́