Sáàmù 98:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jèhófà ti jẹ́ kí á mọ ìgbàlà rẹ̀;+Ó ti mú kí àwọn orílẹ̀-èdè rí òdodo rẹ̀.+ Àìsáyà 11:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ní ọjọ́ yẹn, gbòǹgbò Jésè+ máa dúró bí àmì* fún àwọn èèyàn.+ Ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni àwọn orílẹ̀-èdè máa yíjú sí fún ìtọ́sọ́nà,*+Ibi ìsinmi rẹ̀ sì máa di ológo. Àìsáyà 52:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Jèhófà ti jẹ́ kí wọ́n rí apá rẹ̀ mímọ́ lójú gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè;+Gbogbo ìkángun ayé sì máa rí bí Ọlọ́run wa ṣe ń gbani là.*+ Ìṣe 13:47 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 47 Nítorí Jèhófà* ti pa àwọn ọ̀rọ̀ yìí láṣẹ fún wa pé: ‘Mo ti yàn ọ́ ṣe ìmọ́lẹ̀ àwọn orílẹ̀-èdè, kí o lè jẹ́ ìgbàlà fún gbogbo ayé.’”+
10 Ní ọjọ́ yẹn, gbòǹgbò Jésè+ máa dúró bí àmì* fún àwọn èèyàn.+ Ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni àwọn orílẹ̀-èdè máa yíjú sí fún ìtọ́sọ́nà,*+Ibi ìsinmi rẹ̀ sì máa di ológo.
10 Jèhófà ti jẹ́ kí wọ́n rí apá rẹ̀ mímọ́ lójú gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè;+Gbogbo ìkángun ayé sì máa rí bí Ọlọ́run wa ṣe ń gbani là.*+
47 Nítorí Jèhófà* ti pa àwọn ọ̀rọ̀ yìí láṣẹ fún wa pé: ‘Mo ti yàn ọ́ ṣe ìmọ́lẹ̀ àwọn orílẹ̀-èdè, kí o lè jẹ́ ìgbàlà fún gbogbo ayé.’”+